Lefitiku 26:37 BM

37 Wọn yóo máa ṣubú lórí ara wọn bí ẹni tí ogun ń lé lọ, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé kò sí ẹnikẹ́ni tí ń lé wọn. Kò sì ní sí agbára fun yín láti dúró níwájú àwọn ọ̀tá yín.

Ka pipe ipin Lefitiku 26

Wo Lefitiku 26:37 ni o tọ