Lefitiku 27:24 BM

24 Nígbà tí ó bá di ọdún Jubili, ilẹ̀ yìí yóo pada di ti ẹni tí wọ́n rà á lọ́wọ́ rẹ̀, tí ilẹ̀ yìí jẹ́ ilẹ̀ àjogúnbá rẹ̀ láàárọ̀ ọjọ́.

Ka pipe ipin Lefitiku 27

Wo Lefitiku 27:24 ni o tọ