Lefitiku 3:13 BM

13 kí ó gbé ọwọ́ lé e lórí, kí ó sì pa á níwájú Àgọ́ Àjọ náà; àwọn ọmọ Aaroni yóo sì da ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ sára pẹpẹ náà yípo.

Ka pipe ipin Lefitiku 3

Wo Lefitiku 3:13 ni o tọ