Lefitiku 3:16 BM

16 Kí alufaa sun wọ́n lórí pẹpẹ náà gẹ́gẹ́ bí ẹbọ sísun olóòórùn dídùn. Ti OLUWA ni gbogbo ọ̀rá ẹran.

Ka pipe ipin Lefitiku 3

Wo Lefitiku 3:16 ni o tọ