Lefitiku 3:5 BM

5 Àwọn ọmọ Aaroni yóo sun wọ́n lórí igi tí ó wà ninu iná lórí pẹpẹ; ẹbọ sísun ni, tí ó ní òórùn dídùn, tí inú OLUWA sì dùn sí.

Ka pipe ipin Lefitiku 3

Wo Lefitiku 3:5 ni o tọ