Lefitiku 3:8 BM

8 kí ó gbé ọwọ́ rẹ̀ lé e lórí, kí ó sì pa á níwájú Àgọ́ Àjọ náà; kí àwọn ọmọ Aaroni da ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ sí ara pẹpẹ náà yípo.

Ka pipe ipin Lefitiku 3

Wo Lefitiku 3:8 ni o tọ