12 pátá ni yóo gbé jáde kúrò ninu àgọ́, lọ síbìkan tí ó bá mọ́, níbi tí wọn ń da eérú sí, yóo sì kó igi jọ, yóo dáná sun ún níbẹ̀.
Ka pipe ipin Lefitiku 4
Wo Lefitiku 4:12 ni o tọ