Lefitiku 4:4 BM

4 Yóo mú akọ mààlúù náà wá sí ẹnu ọ̀nà Àgọ́ Àjọ níwájú OLUWA, yóo gbé ọwọ́ lé e lórí, yóo sì pa á níwájú OLUWA.

Ka pipe ipin Lefitiku 4

Wo Lefitiku 4:4 ni o tọ