Lefitiku 4:8 BM

8 Yóo yọ́ gbogbo ọ̀rá akọ mààlúù tí ó fi rú ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ kúrò, ati gbogbo ọ̀rá tí ó bo nǹkan inú rẹ̀;

Ka pipe ipin Lefitiku 4

Wo Lefitiku 4:8 ni o tọ