Lefitiku 6:14 BM

14 “Èyí ni òfin tí ó jẹmọ́ ẹbọ ohun jíjẹ. Àwọn ọmọ Aaroni ni yóo máa rúbọ náà níwájú pẹpẹ, níwájú OLUWA.

Ka pipe ipin Lefitiku 6

Wo Lefitiku 6:14 ni o tọ