Lefitiku 7:3 BM

3 Gbogbo ọ̀rá ara rẹ̀ ni wọ́n gbọdọ̀ fi rúbọ; ìrù tí ó lọ́ràá ati ọ̀rá tí ó bo ìfun rẹ̀,

Ka pipe ipin Lefitiku 7

Wo Lefitiku 7:3 ni o tọ