Lefitiku 7:33 BM

33 Èyíkéyìí ninu àwọn ọmọ Aaroni tí ó bá fi ẹ̀jẹ̀ ati ọ̀rá ẹran náà rúbọ ni ó ni itan ọ̀tún ẹran náà gẹ́gẹ́ bí ìpín tirẹ̀.

Ka pipe ipin Lefitiku 7

Wo Lefitiku 7:33 ni o tọ