Lefitiku 7:9 BM

9 Gbogbo ẹbọ ohun jíjẹ tí a yan ati gbogbo èyí tí a sè ninu apẹ tabi ninu àwo pẹrẹsẹ jẹ́ ti alufaa tí ó fi wọ́n rúbọ.

Ka pipe ipin Lefitiku 7

Wo Lefitiku 7:9 ni o tọ