Lefitiku 8:14 BM

14 Lẹ́yìn náà, ó mú mààlúù ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ jáde, Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀ ọkunrin gbé ọwọ́ lé e lórí.

Ka pipe ipin Lefitiku 8

Wo Lefitiku 8:14 ni o tọ