Lefitiku 8:20 BM

20 Wọ́n gé ẹran àgbò náà sí wẹ́wẹ́, ó sun gbogbo rẹ̀ pẹlu orí rẹ̀ ati ọ̀rá rẹ̀ lórí pẹpẹ.

Ka pipe ipin Lefitiku 8

Wo Lefitiku 8:20 ni o tọ