Lefitiku 9:21 BM

21 Ṣugbọn ó mú àwọn igẹ̀ ẹran náà ati itan ọ̀tún wọn, ó fì wọ́n gẹ́gẹ́ bí ẹbọ fífì níwájú OLUWA, bí Mose ti pa á láṣẹ.

Ka pipe ipin Lefitiku 9

Wo Lefitiku 9:21 ni o tọ