Lefitiku 9:23 BM

23 Mose ati Aaroni bá wọ inú Àgọ́ Àjọ lọ. Nígbà tí wọ́n jáde, wọ́n súre fún àwọn eniyan náà, ògo OLUWA sì yọ sí gbogbo wọn.

Ka pipe ipin Lefitiku 9

Wo Lefitiku 9:23 ni o tọ