Lefitiku 9:9 BM

9 Àwọn ọmọ rẹ̀ sì gbé ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ wá fún un, ó sì ti ìka bọ̀ ọ́, ó fi kan ara ìwo pẹpẹ, ó sì da ẹ̀jẹ̀ yòókù sí ìdí pẹpẹ.

Ka pipe ipin Lefitiku 9

Wo Lefitiku 9:9 ni o tọ