Nọmba 10:14 BM

14 Àwọn tí wọ́n wà lábẹ́ ọ̀págun ẹ̀yà Juda ni wọ́n kọ́kọ́ ṣí, wọ́n tò ní ìsọ̀rí-ìsọ̀rí. Naṣoni ọmọ Aminadabu ni olórí wọn.

Ka pipe ipin Nọmba 10

Wo Nọmba 10:14 ni o tọ