Nọmba 10:25 BM

25 Ní ìparí, àwọn ẹ̀yà tí wọ́n wà lábẹ́ ọ̀págun Dani ṣí, wọ́n tò ní ìsọ̀rí-ìsọ̀rí. Ahieseri ọmọ Amiṣadai ni olórí wọn.

Ka pipe ipin Nọmba 10

Wo Nọmba 10:25 ni o tọ