Nọmba 11:26 BM

26 Meji ninu àwọn olórí náà: Elidadi ati Medadi, kò bá wọn lọ, wọ́n dúró sinu àgọ́ wọn. Ẹ̀mí Ọlọrun bà lé wọn, wọ́n sì ń sọ àsọtẹ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Nọmba 11

Wo Nọmba 11:26 ni o tọ