Nọmba 11:32 BM

32 Àwọn eniyan náà kó ẹyẹ ní ọ̀sán ati ní òru, ẹni tí ó kó kéré jù ni ó kó òṣùnwọ̀n homeri mẹ́wàá. Wọ́n sì sá wọn sílẹ̀ yí ibùdó wọn ká.

Ka pipe ipin Nọmba 11

Wo Nọmba 11:32 ni o tọ