Nọmba 11:34 BM

34 Wọ́n pe orúkọ ibẹ̀ ní Kiburotu Hataafa, èyí tí ó túmọ̀ sí ibojì ojúkòkòrò, nítorí níbẹ̀ ni wọ́n sin òkú àwọn tí wọ́n ṣe ojúkòkòrò ẹran sí.

Ka pipe ipin Nọmba 11

Wo Nọmba 11:34 ni o tọ