Nọmba 12:15 BM

15 Wọ́n sì fi Miriamu sí ẹ̀yìn ibùdó fún ọjọ́ meje, àwọn eniyan náà kò sì kúrò níbẹ̀ títí di ìgbà tí wọ́n mú un pada.

Ka pipe ipin Nọmba 12

Wo Nọmba 12:15 ni o tọ