Nọmba 13:26 BM

26 Wọn tọ Mose, Aaroni, ati àwọn ọmọ Israẹli lọ ní Kadeṣi ní aṣálẹ̀ Parani. Wọ́n sọ gbogbo ohun tí ojú wọn rí, wọ́n sì fi èso tí wọ́n mú wá hàn wọ́n.

Ka pipe ipin Nọmba 13

Wo Nọmba 13:26 ni o tọ