Nọmba 13:30 BM

30 Ṣugbọn Kalebu pa àwọn eniyan náà lẹ́nu mọ́ níwájú Mose, ó ní, “Ẹ jẹ́ kí á lọ nisinsinyii láti gba ilẹ̀ náà, nítorí a lágbára tó láti borí àwọn eniyan náà.”

Ka pipe ipin Nọmba 13

Wo Nọmba 13:30 ni o tọ