Nọmba 14:43 BM

43 Ẹ óo kú nígbà tí ẹ bá ń bá àwọn ará Amaleki ati Kenaani jagun. OLUWA kò ní wà pẹlu yín nítorí pé ẹ ti ṣe àìgbọràn sí i.”

Ka pipe ipin Nọmba 14

Wo Nọmba 14:43 ni o tọ