Nọmba 14:45 BM

45 Àwọn ará Amaleki ati Kenaani tí ń gbé ibẹ̀ bá wọn jagun, wọ́n ṣẹgun àwọn ọmọ Israẹli, wọ́n sì lé wọn títí dé Horima.

Ka pipe ipin Nọmba 14

Wo Nọmba 14:45 ni o tọ