Nọmba 15:26 BM

26 A óo dáríjì gbogbo ìjọ eniyan Israẹli ati àwọn àjèjì tí ń gbé ààrin wọn nítorí pé gbogbo wọn ni ó lọ́wọ́ sí àṣìṣe náà.

Ka pipe ipin Nọmba 15

Wo Nọmba 15:26 ni o tọ