Nọmba 16:10 BM

10 OLUWA ti fún ẹ̀yin ati àwọn ọmọ Lefi yòókù ní anfaani yìí, ṣugbọn nisinsinyii, ẹ̀ ń ṣe ojú kòkòrò sí iṣẹ́ alufaa.

Ka pipe ipin Nọmba 16

Wo Nọmba 16:10 ni o tọ