Nọmba 16:27 BM

27 Àwọn eniyan náà bá kúrò ní agbègbè àgọ́ àwọn Kora ati Datani ati Abiramu.Datani ati Abiramu pẹlu aya ati àwọn ọmọ wọn jáde wá sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ wọn.

Ka pipe ipin Nọmba 16

Wo Nọmba 16:27 ni o tọ