Nọmba 16:33 BM

33 Gbogbo wọn, ati ohun ìní wọn, ati àwọn eniyan wọn, lọ sí ipò òkú láàyè, ilẹ̀ panudé, wọ́n sì ṣègbé kúrò láàrin ìjọ eniyan Israẹli.

Ka pipe ipin Nọmba 16

Wo Nọmba 16:33 ni o tọ