Nọmba 16:39 BM

39 Eleasari bá kó àwọn àwo turari náà tí àwọn tí ó jóná fi rú ẹbọ, ó fi wọ́n rọ àwo fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ fún ìbòrí pẹpẹ.

Ka pipe ipin Nọmba 16

Wo Nọmba 16:39 ni o tọ