Nọmba 17:9 BM

9 Mose kó àwọn ọ̀pá náà jáde kúrò níwájú OLUWA, ó kó wọn wá siwaju àwọn ọmọ Israẹli. Gbogbo wọn wò wọ́n, olukuluku àwọn olórí sì mú ọ̀pá tirẹ̀.

Ka pipe ipin Nọmba 17

Wo Nọmba 17:9 ni o tọ