Nọmba 18:12 BM

12 “Mo fún ọ ní gbogbo èso àkọ́so tí àwọn ọmọ Israẹli ń mú wá fún mi lọdọọdun, ati òróró tí ó dára jùlọ, ọtí waini tí ó dára jùlọ, ati ọkà.

Ka pipe ipin Nọmba 18

Wo Nọmba 18:12 ni o tọ