Nọmba 18:5 BM

5 Ìwọ ati àwọn ọmọ rẹ nìkan ni yóo máa ṣiṣẹ́ ninu ibi mímọ́ ati níbi pẹpẹ, kí ibinu mi má baà wá sórí àwọn ọmọ Israẹli mọ́.

Ka pipe ipin Nọmba 18

Wo Nọmba 18:5 ni o tọ