Nọmba 20:1 BM

1 Ní oṣù kinni, àwọn ọmọ Israẹli dé aṣálẹ̀ Sini, wọ́n sì ṣe ibùdó wọn sí Kadeṣi. Níbẹ̀ ni Miriamu kú sí, tí wọn sì sin ín sí.

Ka pipe ipin Nọmba 20

Wo Nọmba 20:1 ni o tọ