Nọmba 20:15 BM

15 Bí àwọn baba ńlá wa ṣe lọ sí ilẹ̀ Ijipti, tí wọ́n sì gbé ibẹ̀ fún ìgbà pípẹ́. Àwọn ará Ijipti lo àwọn baba ńlá wa ati àwa náà ní ìlò ẹrú.

Ka pipe ipin Nọmba 20

Wo Nọmba 20:15 ni o tọ