Nọmba 21:16 BM

16 Láti ibẹ̀, wọ́n ṣí lọ sí Beeri, níbi kànga tí ó wà níbẹ̀ ni OLUWA ti sọ fún Mose pé, “Pe àwọn eniyan náà jọ, n óo sì fún wọn ní omi.”

Ka pipe ipin Nọmba 21

Wo Nọmba 21:16 ni o tọ