Nọmba 21:6 BM

6 OLUWA bá rán ọpọlọpọ ejò amúbíiná sí àwọn eniyan náà, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí bù wọ́n jẹ, ọpọlọpọ ninu wọn sì kú.

Ka pipe ipin Nọmba 21

Wo Nọmba 21:6 ni o tọ