Nọmba 22:1 BM

1 Àwọn ọmọ Israẹli ṣí kúrò, wọ́n lọ pa àgọ́ wọn sí pẹ̀tẹ́lẹ̀ Moabu ní òdìkejì Jọdani tí ó kọjú sí Jẹriko.

Ka pipe ipin Nọmba 22

Wo Nọmba 22:1 ni o tọ