Nọmba 22:12 BM

12 Ọlọrun sọ fún Balaamu pé, “Má bá wọn lọ, má sì ṣépè lé àwọn eniyan náà nítorí ẹni ibukun ni wọ́n.”

Ka pipe ipin Nọmba 22

Wo Nọmba 22:12 ni o tọ