Nọmba 22:35 BM

35 Angẹli OLUWA sì dáhùn pé, “Máa bá àwọn ọkunrin náà lọ, ṣugbọn ohun tí mo bá sọ fún ọ ni kí o sọ.” Balaamu sì bá wọn lọ.

Ka pipe ipin Nọmba 22

Wo Nọmba 22:35 ni o tọ