Nọmba 22:40 BM

40 Níbẹ̀ ni Balaki ti fi akọ mààlúù ati aguntan ṣe ìrúbọ, ó sì fún Balaamu ati àwọn àgbààgbà tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀ ninu ẹran náà.

Ka pipe ipin Nọmba 22

Wo Nọmba 22:40 ni o tọ