Nọmba 23:11 BM

11 Nígbà náà ni Balaki sọ fún Balaamu pé, “Kí ni ò ń ṣe sí mi yìí? Mo mú ọ wá láti ṣépè lé àwọn ọ̀tá mi, ṣugbọn ò ń súre fún wọn.”

Ka pipe ipin Nọmba 23

Wo Nọmba 23:11 ni o tọ