Nọmba 23:21 BM

21 Kò rí ìparun ninu Jakọbu,bẹ́ẹ̀ ni kò rí ìpọ́njú níwájú Israẹli.OLUWA Ọlọrun wọn wà pẹlu wọn,Òun sì ni ọba wọn.

Ka pipe ipin Nọmba 23

Wo Nọmba 23:21 ni o tọ