Nọmba 23:9 BM

9 Mo rí wọn láti òkè gíga,mò ń wò wọ́n láti orí àwọn òkè.Wọ́n jẹ́ orílẹ̀-èdè tí ń dá gbé;wọn kò da ara wọn pọ̀ mọ́ àwọn orílẹ̀-èdè yòókù.

Ka pipe ipin Nọmba 23

Wo Nọmba 23:9 ni o tọ