Nọmba 24:20 BM

20 Nígbà tí ó wo Amaleki, ó fi òwe sọ̀rọ̀ nípa wọn báyìí pé:“Amaleki ni orílẹ̀-èdè tí ó lágbára jùlọ,Ṣugbọn yóo ṣègbé níkẹyìn.”

Ka pipe ipin Nọmba 24

Wo Nọmba 24:20 ni o tọ