Nọmba 25:1 BM

1 Nígbà tí àwọn ọmọ Israẹli pàgọ́ sí àfonífojì Ṣitimu, àwọn ọkunrin wọn ń bá àwọn ọmọbinrin Moabu tí wọ́n wà níbẹ̀ ṣe àgbèrè.

Ka pipe ipin Nọmba 25

Wo Nọmba 25:1 ni o tọ