Nọmba 25:6 BM

6 Ọ̀kan ninu àwọn ọmọ Israẹli mú ọmọbinrin Midiani wọlé lójú Mose ati gbogbo àwọn eniyan, níbi tí wọ́n ti ń sọkún lẹ́nu ọ̀nà Àgọ́ Àjọ níwájú OLUWA.

Ka pipe ipin Nọmba 25

Wo Nọmba 25:6 ni o tọ